Oriki Olodumare Olorun (Oruko ati Oriki Olorun): Names of God in Yoruba Language, Praise Names, God’s Names in Yoruba Oluwa, (Lord) Oluwa wa, (Our Lord) Olorun, (God) Olorun wa, (Our God) Oluwa awon oluwa, (The Lord of Lords) Olorun awon olorun, Kabiyeesi, (The King) Oba awon oba,( King of Kings) Olodumare,( The Almighty) Arugbo ojo,(Ancient of days) Olorun agbalagba,( Ancient of days) Adagba ma paaro oye,(Unchanging God) Olorun ti o yipada, (Unchanging God) Olorun kan lailai,( The only God) Ikan lana,(Same yesterday) Ikan loni, (Same today) Ikan lola, (Same tomorrow) Okan titi aye ainipekun, ( The same forever) Oba ti mbe nibi gbogbo nigba gbogbo,( the ubiquitous God) Metalokan,( The trinity) Olorun Baba,(God the Father) Olorun Omo,(God the son) Olorun Emi Mimo, (God the Holy spirit) Olorun Abrahamu, (God of Abraham) Olorun Isaki, (God of Isaac) Olorun Jakobu, (God of Jacob) Olorun owu,(The jealous God) Olorun ti kii s’enia ti yio paro, (God that ...