Name Of Months And Days In Yoruba

Months
January: Oṣù Ṣẹ́rẹ́ (Ṣẹ́rẹ́, 1)
February: Oṣù Èrèlè (Èrèlè, 2)
March: Oṣù Ẹrẹ̀nà (Ẹrẹ̀nà, 3)
April: Oṣù Ìgbé (Ìgbé, 4)
May: Oṣù Ẹ̀bibi (Ẹ̀bibi, 5)
June: Oṣù Òkúdu (Òkúdu, 6)
July: Oṣù Agẹmọ (Agẹmọ, 7)
August: Oṣù Ògún (Ògún, 8)
September: Oṣù Owewe (Owewe, 9)
October: Oṣù Ọ̀wàrà (Ọ̀wàrà, 10)
November: Oṣù Bélú (Bélú, 11)
December: Oṣù Ọ̀pẹ̀ (Ọ̀pẹ̀, 12)

Days
Sunday: Ọjọ́ Àìkú (Àìkú)
Monday: Ọjọ́ Ajé (Ajé)
Tuesday: Ọjọ́ Ìsẹ́gun (Ìsẹ́gun)
Wednesday: Ọjọ́rú (Ọjọ́rú)
Thursday: Ọjọ́bọ (Ọjọ́bọ)
Friday: Ọjọ́ Ẹtì (Ẹtì)

Saturday: Ọjọ́ Àbámẹ́ta (Àbámẹ́ta)

Comments

  1. E ku ise o eyin omo Oodua tooto. E ma jakan ninu ise yii, yoo so eso rere nigbeyin

    ReplyDelete
  2. Thanks for this really help me a lot of thanks again and put mor effort

    ReplyDelete
  3. Thank you for your help 😍😍😍

    ReplyDelete

Post a Comment

Popular posts from this blog

Spirits Spouse - Solution for Oko Orun (spiritual husband problems)

SPELL TO ATTRACT WOMEN TO YOU (AWURE OBINRIN)

WAYS AND MEDICINE TO OVERCOME THE SPIRIT OF ANXIETY AND FEAR